Categories
ORIN SOLOMONI

ORIN SOLOMONI Ọ̀rọ̀ Iṣaaju

Ọ̀rọ̀ Iṣaaju

Ewì ìfẹ́ ni

Orin Solomoni

, nítorí ọpọlọpọ orin tí ó wà ninu rẹ̀ jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ìfẹ́ láàrin ọkunrin kan ati obinrin kan tí wọ́n jẹ́ olólùfẹ́. Àwọn ìwé mìíràn pè é ní Orin Solomoni, nítorí pé àwọn Heberu ka ọ̀rọ̀ orin náà kún orin tí Solomoni kọ. Àwọn mìíràn sì ń pè é ní “Orin tí ó dùn jùlọ.”

Àwọn Juu ń fi ojú àjọṣe láàrin Ọlọrun ati àwọn eniyan rẹ̀ wo àwọn orin wọnyi, ṣugbọn ojú àjọṣe láàrin Kristi ati ìjọ ni àwọn Kristẹni fi wò wọ́n.

Àwọn Ohun tí ó wà ninu Ìwé yìí ní Ìsọ̀rí-ìsọ̀rí

Orin kinni 1:1–2:7

Orin keji 2:8–3:5

Orin kẹta 3:6–5:1

Orin kẹrin 5:2–6:3

Orin karun-un 6:4–8:4

Orin kẹfa 8:5-14

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *